(Lyrics) Brymo – Méjì Méjì

(Lyrics) Brymo – Méjì Méjì
(Lyrics) Brymo – Méjì Méjì

Brymo – Méjì Méjì Lyrics

Mofiye fo, mo rire
Mowaju mowoke, Ire de
Kijo mole, Motun taka sufe

O dun mo mi oh
O dun mo mi oh
O dun mo mi oh
O dun mo mi oh

Chorus
Meji Meji ladaye oh (Meji Meji ladaye oh)
Ife re simi O jin gan gan (Meji Meji ladaye oh)
Meji Meji ladaye oh (Meji Meji ladaye oh)
Ife re simi O jin gan gan (Meji Meji ladaye oh)

Ore dakun ro koto lo
Motaraka mo subu
Ki n to ko ohun mo n so
Yara gboro, Lora fesi
Esin o gbani, Iwa o Lani
Ohun to wun ni lo n wani
Ore dakun ro koto lo
Motaraka mo subu
Ki n to mo ohun mo n so
Yara gboro, lora fesi
Esin o gbani, Iwa o lani
Ohun to wun ni lo n wani

Mofiye fo, mo rire
Mowaju mowoke, Ire de
Kijo mole, Motun taka sufe

O dun mo mi oh
O dun mo mi oh
O dun mo mi oh
O dun mo mi oh

Meji Meji ladayе oh (Meji Meji ladaye oh)
Ifе re simi O jin gan gan (Meji Meji ladaye oh)