(Lyrics) Brymo – Fura Sára

(Lyrics) Brymo – Fura Sára
(Lyrics) Brymo – Fura Sára

 

Brymo – Fura Sára Lyrics

O pami lekun
O wa funmi l’akara je
Mo sunkun, mo gbonju
O ni sare lo soja
Bo wun mi n bugije

Ah ah ah ah ah ah ah

Olo mi dakun jowo oh
Dakun jowo oh
Ye gbo telegan
Ye gbo telegan
Ye gbo telegan
Fura siwo

O gba’ja onija ja
O n ja f’arata
Bobaya wa danu gbaga
A le mi ni mo se aida

Ah ah ah ah ah ah ah

Obirin yii dakun jowo oh
Dakun jowo oh
Ye gbo telegan
Ye gbo telegan
Ye gbo telegan
Fura Sara