(Lyrics) Brymo – Alelúyà Méje

(Lyrics) Brymo – Alelúyà Méje
(Lyrics) Brymo – Alelúyà Méje

 

Brymo – Alelúyà Méje Lyrics

Aleluya meje meje
Oselu pejo fun ojo meje
Won fe to’lu lojo meje
Gbogbo isele korin kese
Aleluya meje meje
Awon ojelu fere ge
Won l’awon omo epa tun tide
Won fe darulu mere le

Aleluya meje meje
Akoni leru won tun ti de
Won fe so bose mama gbe
Iwo n foku sorun O n sise agbе
Gbogbo isele korin kesе
Won l’awon omidan lo maye le
Won fe jeka won fe roso
Oko loma ye okunrin le

Bo kowaju si e kota
Boba keyin si e kota
Boba kuwo nikan se hun o le se
Ma gbagbe ibi o ti babo
Bo kowaju si e kota
Boba keyin si e kota
Boba kuwo nikan se hun o le se
Ma gbagbe ibi o ti babo

Aleluya meje meje (Arere epa epa)
Adaleru won tun ti de (Arere epa epa)
Ko fe k’omo o mo baba re (Arere epa epa)
Ko fe k’oko ko gbo t’aya re (Arere epa epa)
Gbogbo isele korin kese (Arere epa epa)
Won l’awon omidan lo maye le (Arere epa epa)
Won fe jeka won fe roso (Arere epa epa)
Oko loma ye okunrin le (Arere epa epa)